Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 17:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún wọ́n pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ẹ̀yin Ọba Júdà àti gbogbo ẹ̀yin ènìyàn Júdà àti gbogbo ẹ̀yin tí ń gbé ní Jérúsálẹ́mù tí ń wọlé láti ẹnu-bodè yìí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 17

Wo Jeremáyà 17:20 ni o tọ