Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 17:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ẹ̀ṣẹ̀ Júdà ni a fi ṣóóṣó irin kọ sílẹ̀èyí tí ó hàn ketekete pẹ̀lú ẹnu ṣóróṣórósí oókan àyà wọn, àti lórí àwọn ìwotó wà lórí pẹpẹ wọn.

2. Kódà àwọn ọmọ wọn rántí pẹpẹàti òpó Áṣérà lẹ́bàá igi tí ó tẹ́ rẹrẹàti àwọn òkè gíga.

3. Àwọn òkè nínú ilẹ̀ àti àwọn ọrọ̀ rẹ̀àti ọlá rẹ̀ ni èmi yóò fi sílẹ̀ bí ìjẹpẹ̀lú àwọn ibi gíga, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ópọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 17