Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn yóò kú ikú àrùn, wọn kò ní sin wọ́n tàbí sọ̀fọ̀ fún wọn. Wọn ó dàbí ìdọ̀tí lórí ilẹ̀; wọn ó ṣègbé pẹ̀lú ọ̀kọ̀ àti ìyàn. Òkú wọn yóò sì di oúnjẹ fún ẹyẹ ojú ọ̀run àti ẹranko ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 16

Wo Jeremáyà 16:4 ni o tọ