Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n gbààwẹ̀, èmi kò ní tẹ́tí sí igbe wọn. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n rúbọ ọrẹ sísun àti ẹbọ ọkà, èmi ò ní gbà wọ́n. Dípò bẹ́ẹ̀, èmi ó fi idà, ìyànu àti àjàkálẹ̀-àrùn pa wọ́n run.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 14

Wo Jeremáyà 14:12 ni o tọ