Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí a ti lẹ àmùrè mọ́ ẹ̀gbẹ́ ènìyàn, bẹ́ẹ̀ ni a lẹ agbo ilé Ísírẹ́lì àti gbogbo ilé Júdà mọ́ mi,’ ni Olúwa wí, ‘kí wọn kí ó lè jẹ́ ènìyàn ògo àti ìyìn fún mi, ṣùgbọ́n wọn kò fẹ́ gbọ́.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 13

Wo Jeremáyà 13:11 ni o tọ