Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò ti pẹ́ tó tí ọ̀gbẹlẹ̀ yóò fi wà,tí gbogbo ewéko ìgbẹ́ sì ń rọ?Nítorí àwọn ènìyàn búburú ni ó ń gbé ibẹ̀.Àwọn ẹranko àti àwọn ẹyẹ ti ṣègbé,pẹ̀lúpẹ̀lú àwọn ènìyàn ń sọ pé,“Kò lè rí ohun tó ṣẹlẹ̀ síwa.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:4 ni o tọ