Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n bá sì kọ ìwà àwọn ènìyàn mi, tí wọ́n sì fi orúkọ mi búra wí pé, ‘Olúwa ń bẹ,’ gẹ́gẹ́ bí ó ti dájú pé, Olúwa wà a kọ́ ènìyàn mi láti fi Báálì búra, nígbà náà ni a ó gbé wọn ró láàrin ènìyàn mi.

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:16 ni o tọ