Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 11:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún wọn wí pé èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: ‘Ègbé ni fún ẹni náà tí kò pa ọ̀rọ̀ májẹ̀mú yìí mọ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 11

Wo Jeremáyà 11:3 ni o tọ