Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n nàró bí igi ọ̀pẹ, òrìṣà wọnkò le è ṣọ̀rọ̀. Wọ́n gbọdọ̀ máa gbéwọn nítorí pé wọn kò lè rìn. Má ṣebẹ̀rù wọn; wọn kò le è ṣe ibi kankanbẹ́ẹ̀ ni wọn kò si lè ṣe rere kan.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 10

Wo Jeremáyà 10:5 ni o tọ