Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì ti ṣetán láti pe gbogbo àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè àríwá níjà,” ni Olúwa wí.Àwọn Ọba wọn yóò wágbé ìtẹ́ wọn ró ní ojú-ọ̀nà à bá wọléJérúsálẹ́mù. Wọn ó sì dìde sí gbogboàyíká wọn àti sí gbogbo àwọnìlú Júdà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 1

Wo Jeremáyà 1:15 ni o tọ