Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Olúwa wí pé “Èmi yóò pa ènìyàn tí mo ti dá run kúrò lórí ilẹ̀, ènìyàn àti ẹranko, àti ohun tí ń rákò, àti ẹyẹ ojú ọ̀run, nítorí inú mi bàjẹ́ pé mo ti dá wọn.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 6

Wo Jẹ́nẹ́sísì 6:7 ni o tọ