Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 50:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣẹ́fù sì mú kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì búra májẹ̀mu kan wí pé, “Dájúdájú Ọlọ́run yóò wá sí ìrànlọ́wọ́ yín, nígbà náà ni ẹ gbọdọ̀ kó egungun mi lọ́wọ́ kúrò ní ìhín.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 50

Wo Jẹ́nẹ́sísì 50:25 ni o tọ