Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 48:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańgẹ́lì tí ó ti gbà mí kúrò lọ́wọ́ gbogbo ewu,kí ó súre fún àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí.Kí a máa fi orúkọ́ mi pè wọ́n àti orúkọ àwọn baba miÁbúráhámù àti Ísáákì,kí wọn kí ó sì pọ̀ sí i lọ́pọ̀lọpọ̀lórí ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 48

Wo Jẹ́nẹ́sísì 48:16 ni o tọ