Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 46:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jákọ́bù kúrò ní Báá-Ṣébà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì mú Jákọ́bù bàbá wọn àti àwọn aya wọn àti àwọn ọmọ wọn, wọ́n sì kó wọn sí inú kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Fáráò fí ránsẹ́ fún ìrìn-àjò rẹ̀:

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46

Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:5 ni o tọ