Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 46:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹ fún-un lésì pé, “àwọn ìránṣẹ́ rẹ ń tọ́jú ẹran-ọ̀sìn ni láti ìgbà ewe wa wá gẹ́gẹ́ bí a ṣe ba a lọ́wọ́ àwọn baba wa.” Nígbà náà ni wọn yóò fún un yín láàyè láti tẹ̀dó sí ilẹ̀ Gósénì. Nítorí pé àwọn ará Éjíbítì kóríra ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́ darandaran.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46

Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:34 ni o tọ