Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 46:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jósẹ́fù wí fún àwọn arákùnrin rẹ̀ àti fún àwọn ará ilé baba rẹ̀ pé, “Èmi yóò gòkè lọ, èmi yóò sì bá Fáráò sọ̀rọ̀, èmi yóò sì wí fún-un pé, Àwọn arákùnrin mi àti ìdílé baba mi tí ń gbé ní Kénánì ti tọ̀ mí wá.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46

Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:31 ni o tọ