Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 36:22-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Àwọn ọmọ Lótanì:Órì àti Ómámù: Arábìnrin Lótanì sì ni Tímínà.

23. Àwọn ọmọ Ṣóbálì:Álífánì, Mánáhátì, Ébálì, Ṣéfò àti Onámù.

24. Àwọn ọmọ Ṣíbéónì:Áíyà àti Ánà. Èyí ni Ánà tí ó rí ìṣun omi gbígbóná ní inú asálẹ̀ bí ó ti ń da àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Ṣébéónì baba rẹ̀.

25. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Ánà:Dísónì àti Óhólíbámà (Àwọn ọmọbìnrin ni wọn).

26. Àwọn ọmọ Dísónì ni:Hémídánì, Ésíbánì, Ítíránì àti Kéránì.

27. Àwọn ọmọ Éṣérì:Bílíhánì, Ṣááfánì, àti Ákánì.

28. Àwọn ọmọ Díṣánì ni Húsì àti Áránì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 36