Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 31:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rákélì sì gbé àwọn òrìṣà náà sínú gàárì ràkunmí, ó sì jókòó lé e lórí. Lábánì sì wá gbogbo inú àgọ́, kò sì rí ohunkóhun.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 31

Wo Jẹ́nẹ́sísì 31:34 ni o tọ