Ó sì tún lóyún, ó sì tún jẹ́ pé ọmọkùnrin ni ó bí, ó sì wí pé, “Nígbà yìí ni èmi yóò yin Olúwa” Ó sì pe orukọ rẹ̀ ní Júdà. Ó sì dáwọ́ ọmọ bíbí dúró.