Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí obìnrin náà kò bá fẹ́ tẹ̀lé ọ wá, nígbà náà ni a tú ọ sílẹ̀ kúrò nínú ìbúra yìí, ṣùgbọ́n pàtàkì ni pé ìwọ kò gbọdọ̀ mú ọmọ mi padà lọ sí ibẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:8 ni o tọ