Jẹ́nẹ́sísì 18:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ábúráhámù wí pé, “Níwọ̀n bí mo ti ní ìgboyà láti bá Olúwa sọ̀rọ̀ báyìí, jẹ́ kí n tẹ̀ṣíwájú. Bí o bá ṣe pé olódodo ogún péré ni ó wà nínú ìlú náà ńkọ́?” Olúwa sì dáhùn pé, “Èmi kì yóò pa á run nítorí ogún ènìyàn náà.”