Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 15:18-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Ní ọjọ́ náà gan-an ni Olúwa dá májẹ̀mú pẹ̀lú Ábúrámù, ó sì wí pé, “Àwọn ìran rẹ ni èmi yóò fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Éjíbítì dé odò ńlá Yúfúrátè:

19. ilẹ̀ àwọn ará Kénì, Kádímónì,

20. Ítì, Pérísísì, Réfáímù.

21. Ámórì, Kénánì, Gírígásì àti Jébúsì.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15