Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jẹ́nẹ́sísì 15:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn èyí, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Ábúrámù wá lójú ìran pé:Ábúrámù má ṣe bẹ̀rù,Èmi ni ààbò rẹ,Èmi sì ni èrè ńlá rẹ.

2. Ṣùgbọ́n Ábúrámù wí pé, “Olúwa, alágbára, kí ni ìwọ yóò fi fún mi níwọ̀n ìgbà tí èmi kò bímọ, Élíásérì ará Dámásíkù ni yóò sì jogún mi,”

3. Ábúrámù sì tún tẹ̀ṣíwájú pé, “Ìwọ kò fún mi ní ọmọ, nítorí náà ẹrú nínú ilé è mi sì ni yóò jẹ́ àrólé mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15