Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dá mi lóhùn pé, “Ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì àti Júdà pọ gan an ni; ilé wọn kún fún ìtàjẹ̀sílẹ̀ àti àìsòótọ́. Wọ́n ní, ‘Olúwa tí kọ ilẹ̀ náà sílẹ̀; Olúwa kò sì rí wa.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 9

Wo Ísíkẹ́lì 9:9 ni o tọ