Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, gbójú sókè sí ìhà àríwá.” Èmi náà sì gbójú sókè sí ìhà àríwá mo sì rí ère tí ó ń mú ni jowú ní ẹnu ọ̀nà ibi pẹpẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:5 ni o tọ