Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó na ohun tó dàbí ọwọ́ jáde, ó fi gba mi nírun orí mú, Ẹ̀mí sì gbé mi sókè sí agbede-méjì ayé àti ọ̀run, ó sì mú mi lọ rí ìran Ọlọ́run, mo sì lọ sí Jérúsálẹ́mù, sí ìlẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà òde àríwá níbi tí ère tí ó ń mú ni bínú wá níwájú mi,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:3 ni o tọ