Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú mi wá sí ẹnu ọ̀nà ilé Olúwa tó wà ní ìhà àríwá, mo sì rí àwọn obìnrin tó jókòó, tí wọ́n sí ẹnu ọ̀nà ilé Olúwa tó wà ní ìhà àríwá, mo sì rí àwọn obìnrin tó jókòó, tí wọ́n sì ń ṣọ̀fọ̀ fún Támúrì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:14 ni o tọ