Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 7:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba yóò sọ̀fọ̀, ọmọ aláde yóò wà láì ní ìrètí ọwọ́ àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà yóò wárìrì. Èmi yóò ṣe é fún wọn gẹ́gẹ́ bí ìṣe wọn, èmi yóò ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí ìgbékalẹ̀ wọn, nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé èmi ní Olúwa.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:27 ni o tọ