Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Idà wà níta, àjàkálẹ̀-àrùn àti ìyàn wà nílé, idà yóò pa ẹní tó bá wà ní orílẹ èdè, àjàkálẹ̀-àrùn àti ìyàn yóò pa ẹni tó bá wà ní ìlú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:15 ni o tọ