Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O ó wá di ẹ̀gàn, ẹ̀sín àti ikílọ àti ohun ẹ̀rù àti ìyanu fún àwọn orílẹ̀ èdè tó yí ọ ká nígbà tí mo bá fìyà jẹ ọ́ nínú ìbínú àti nínú ìbínú gbígbóná mi. Èmi Olúwa ni ó sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:15 ni o tọ