Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdá mẹ́ta nínú àwọn ènìyàn rẹ yóò kú nípa àjàkálẹ̀-àrùn tàbí kí ìyàn run wọ́n: ìdá mẹ́ta yóò ṣubú nípa idà lẹ́yìn odi rẹ n ó sì tú ìdá mẹ́ta yóòkù ká sínú èfúùfù, a ó sì máa fi idà lé wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:12 ni o tọ