Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí, ọmọ ènìyàn, mú ìdá tí ó mú kí o sì fi se abẹ ìfárí onígbàjámọ̀, kí o fi fá irun orí àti irùngbọ̀n rẹ. Fi irun yìí sórí ìwọ̀n kí o sì pín in.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:1 ni o tọ