Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 48:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìhà ìlà oòrùn, èyí tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ni ojú ọ̀nà mẹ́ta yóò wà: ọ̀nà Jósẹ́fù, ọ̀nà tí Bẹ́ńjámínì àti ọ̀nà tí Dánì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:32 ni o tọ