Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 48:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí tí ó sẹ́kù ni ẹ̀gbẹ́ méjèèjì agbégbé tí ó jẹ́ ìpín ibi mímọ́ àti ohun ìní ìlú ńlá náà yóò jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé. Yóò lọ títí dé ìhà ìlà oòrùn láti ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ti ìpín ibi mímọ́ títí dé ààlà ìlà oòrùn. Agbégbé méjèèjì wọ̀nyí ni gígùn àwọn ìpín ẹlẹ́yàmẹ́yà yóò jẹ́ ti àwọn ọmọ aládé, àti ìpín ibi mímọ́ pẹ̀lú tẹ́ḿpìlì yóò wa ní àárin wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:21 ni o tọ