Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún mi pé, “Odò yìí ń ṣàn sí ìhà ìlà oòrùn, ó sì lọ sí ìsàlẹ̀ títí dé Árábù, níbi tí ó ti wọ inú òkun, omi tí o wà níbẹ̀ jẹ́ èyí tí ó tutù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:8 ni o tọ