Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wọn ẹgbẹ̀rún ìgbọ̀nwọ́ mìíràn kúrò, ṣùgbọ́n nísinsìnyí odò tí ń kò lè kọjá rẹ̀ ni, Nítorí pé odò tí ó kún, ó sì jìn tó èyí tí wọ́n le lúwẹ̀ẹ́ nínú rẹ̀ odò tí ẹnikẹ́ni kò le dá kọjá ni.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:5 ni o tọ