Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọkùnrin náà ti lọ sí apá ìhà ìlà oòrùn pẹ̀lú okùn wíwọ̀n nǹkan lọ́wọ́ rẹ̀, o wọn ẹgbẹ̀rún ìgbọ̀nwọ́, ó sì mú mi gba ibi odò kan tí kòì jìnjù kókósẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:3 ni o tọ