Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:22-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Ìwọ yóò pín gẹ́gẹ́ bí ìní fún ara yín àti fún àwọn àjòjì tí ó ń gbé ní àárin yín tí ó sì ní àwọn ọmọ. Ìwọ yóò sì ṣe sí wọn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìbílẹ̀ àwọn ará Ísírẹ́lì; papọ̀ mọ́ yin ni kí a pín ìní fún wọn ní àárin àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.

23. Ní àárin ẹ̀yàkẹyà tí àwọn àlejò ń gbé; wọn gbọdọ̀ fi ìní tirẹ̀ fún-ún,” ní Olúwa Ọba pa lásẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47