Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò pín ilẹ̀ náà déédéé ní àárin wọn. Nítorí pé mo búra nípa nína ọwọ́ sókè láti fi fún àwọn baba ńlá yin, ilẹ̀ yìí yóò di ogún ìní yín.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:14 ni o tọ