Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 47:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn igi eléso ní oríṣìíríṣìí ni yóò dàgbà ní bèbè odò méjèèjì. Ewé wọn kì yóò sì gbẹ, tàbí ní èso nítorí pé odò láti ibi mímọ́ ń ṣàn sí wọn. Èso wọn yóò dàbí oúnjẹ àti ewé wọn fún ìwòsàn.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 47

Wo Ísíkẹ́lì 47:12 ni o tọ