Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbègbè kan tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní fífẹ̀ yóò jẹ́ ti àwọn ará Léfì, tí ó ń ṣiṣẹ ìránṣẹ́ nínú tẹ́ḿpìlì, gẹ́gẹ́ bi ìní wọn fún ìlú wọn láti máa gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:5 ni o tọ