Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò jẹ́ ojúṣe ọmọ aládé láti pèsè ọrẹ ẹbọ sísun, ọrẹ ẹbọ jíjẹ àti ọrẹ ẹbọ mímu níbi àṣè gbogbo, ti oṣù tuntun àti ní àwọn ọjọ ìsìnmi ni gbogbo àjọ ilé Ísírẹ́lì. Oun yóò pèsè ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ọrẹ ẹbọ jíjẹ, ọrẹ ẹbọ sísun àti ọrẹ ẹbọ ìdàpọ̀, láti ṣe ètùtù fún ilé Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:17 ni o tọ