Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà ni àwa yóò mú àgùntàn kan láti inú agbo ẹran tí ó jẹ́ igba láti inú kanga omi pápá oko tútù tí Ísírẹ́lì. Ìwọ̀nyí ni wọn yóò lò fún àwọn ọrẹ ẹbọ jíjẹ, ẹbọ sísun àti ìdàpọ̀ ọrẹ ẹbọ láti ṣe ìwẹ̀nùmọ́ fún àwọn ènìyàn, ní Olúwa Ọba sọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:15 ni o tọ