Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àfikún pẹ̀lú gbogbo àwọn ìwà ìríra rẹ tí ó kù, ìwọ mú àwọn àjòjì aláìkọlà àyà àti ara wá sí inú ibi mímọ́ mi, ní lílo ilé mi ní ìlòkúlò nígbà tí ìwọ fi oúnjẹ fún mi, ọ̀rá àti ẹ̀jẹ̀, ìwọ sì ba májẹ̀mú mi jẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:7 ni o tọ