Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àlùfáà kò gbọdọ̀ jẹ́ ohunkóhun bí i ẹyẹ tàbí ẹrankọ, tí ó ti kú fúnra rẹ̀ tàbí èyí ti ẹranko ńlá fà ya.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:31 ni o tọ