Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn le sìn mi ní ibi mímọ́ mi, kí wọn ṣe ìtọ́jú àwọn ẹnu ọ̀nà ilé Ọlọ́run, kí wọn sì ṣe ìránṣẹ́ nínú rẹ̀; wọn le pa ẹbọ sísun, ki wọn sì rúbọ fún àwọn ènìyàn, kí wọn sì dúró níwájú àwọn ènìyàn, kí wọ́n sì ṣe ìránṣẹ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:11 ni o tọ