Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọkùnrin náà dúró ní ẹ̀gbẹ́ mi, mo gbọ́ ẹnìkan tí ó bá mi sọ̀rọ̀ láti inú ilé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:6 ni o tọ