Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọjọ́ méje wọn yóò jẹ́ ètùtù fún pẹpẹ, wọn yóò sì sọ ọ́ di mímọ́; nípa bẹ́ẹ̀ wọn yóò yà á sọ́tọ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:26 ni o tọ