Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igun ni apá òkè náà jẹ́ igun mẹ́rin lọ́gbọgba, ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rìnlá ní gígùn, ó sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rìnlá ní fífẹ̀, pẹ̀lú etí tí ó jẹ́ ìdáji ìgbọ̀nwọ́, ìsàlẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan yípo. Àtẹ̀gùn pẹpẹ ìrúbọ náà dojúkọ ìlà oòrùn.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:17 ni o tọ