Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 43:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìsàlẹ̀ rẹ̀ ni ilẹ̀ títí dé ìsàlẹ̀ igun rẹ̀, ó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì ni gíga o sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ní fífẹ̀:

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:14 ni o tọ